11s 10s (FE 682) “Ife lakoja ofin" - 1Kor. 13:13 Tune: Emi l'Olorun awon ti ba nsin 1. IFE pipe t’o tayo ero eda L’ebe l’a kunle niwaju ‘te Re Jowo f’ife ti ki y’o lopin sarin Awon t’lwo so sokan po lailai. 2. lye pipe jowo f‘aiya won bale Nipa ife ati ‘gbagbo yiye Ti suru, ireti, at’ifarada Pelu igbekele ti ko le ye. 3. Jo fun won l’ayo ti y’o m‘aiye won dun Alafia ti y’o segun ija Si f’ife aiyeraiye ati Iye Kun okan won titi d‘ojo Ogo. Amin