HYMN 650

SSS 874 C.M.S 438. S 338
P.M (FE 676)
"Eje Jesu Kristi" - 1John 1:7




1.  KIL’o le w’ese mi nu 

     Ko si lehin eje Jesu 

     Kil' o tun le wo mi san 

     Ko si, lehin eje Jesu.

Egbe: A! eje yebiye 

          T'o mu mi fun bi sno

          Ko si sun miran mo 

          Ko si, lehin eje Jesu.


2.  Fun wenumo mi,nko ri 

     Nkan mi, lehin eje Jesu 

     Ohun ti mo gbekele 

     Fun dariji l’eje Jesu. 

Egbe: A! eje yebiye...


3.  Etutu f’ese ko si 

     Ko si lehin eje Jesu 

     lse rere kan ko si 
   
     Ko si, lehin eje Jesu. 

Egbe: A! eje yebiye...


4.  Gbogbo igbekele mi 

     lreti mi l'eje Jesu 

     Gbogbo ododo mi ni 

     Eje, kiki eje Jesu.

Egbe: A! eje yebiye 

          T'o mu mi fun bi sno

          Ko si sun miran mo 

          Ko si, lehin eje Jesu.  Amin

English »

Update Hymn