L.M (FE 675) “Nje gbogbo eniti ongbe ngbe o wa sibi omi" - Isa.55:1 1. GBOGBO eni t’ongbe ngbe wa! Olorun npe gbogb’ elese Ra anu on ‘gbala lofe Ra or‘ofe ihinrere. 2. Wa s’ibi omi iye wa Elese je pe ‘Eleda Pada, asako, bo wa ‘le Ofe ni ore mi fun nyin! 3. Wo Apata ti nsun jade Isun ‘marale nsan fun o Enyin ti eru ese npa E wa, l'aimo owo lowo. 4. Ko s’iparo t’e le mu wa E f’ini nyin gbogbo sehin F'igboiya gb’ebun Olorun Ni idariji n’nu Jesu. Amin