HYMN 641

t. H.C 2nd Ed.502. C.M (FE 667)
“Ore ofe ki o wa pelu nyin" - 2Tim. 4:22



1.  F'ore-ofe Re ba wa gbe 

     Jesu Olugbala

     Ki eni arekereke

     K'o ma le kolu wa.


2.  F'oro mimo Re ba wa gbe 

     Jesu iyebiye

     K'a ri igbala on iye 

     Lohun bi nihinyi.


3.  Fi ‘bukun Tiure ba wa gbe 

     Oluwa Oloro

     Fi ebun orun rere Re 

     Fun wa l’opolopo.


4.  Fi pamo Tire ba wa gbe

     Iwo Alagbara

     K‘awa k'o le sa ota ti

     K’aiye k’o ma de wa.


5.  Fi otito Re ba wa gbe 

     Olorun Olore

     Ninu ponju wa ba wa re 

     Mu wa fi ori ti.


6.  F‘alafia re ba wa gbe 

     Nigbat‘iku ba de 

     N'iseju na, so fun wa pe 

     lgbala nyin ti de.  Amin

English »

Update Hymn