HYMN 64
Tune: Oluwa agbara fohun
1. ’BUKUN ni f’awon mimo
Won ti ko ‘se angeli
Orun n’ife okan won
Won fe lati r’Olorun
A we abawon won nu
Won n'idapo pelu Re
Won dabi Oluwa won
Ti ise ere nla fun won.
2. Won n’josin ninu emi
Won wole ni’bi'te Re
Won te ba nib‘imole
lmole Olorun tan
Awon olokan-riro
Ti won fe lati kekoo
Won wa inu Oro naa
Titi won fi gb’ohun Re.
3. Oun ni Eleda won
Won ba Oun nikan soro
Lat‘ooro di asale
Ni won nyin l'Ojo ‘sinmi
Won di Ii mu ninu laalaa
Won gbekele e n'nu ‘ponju
lmole Re n tan n'nu won
Ayida ko bori re.
4. Oun ni won n yin l'aye won
Won ki yoo ri iku mo
Won yoo maa b'Oluwa gbe
Titi won yoo fi jinde
Won yoo sunmo Oluwa
Pelu ara ajinde
Pelu Baba n'nu Omo
At’Emi, metalokan. Amin
English »Update Hymn