HYMN 633

H.C. 520 C.M (FE 659)
"Tire l'emi gbamilla" - Ps 119:94



1.  TIRE titi lai l'awa se

     Oluwa wa orun

     K'ohun at'okan wa wipe

     Amin, beni k'o ri.


2.  Gbati aiye ba ndun mo ni 

     T'o si nfa okan wa

     K'iro yi pe, 'Tire l’awa 

     Lema dun l'eti wa.


3.  Gbat' ese pelu etan re 

     Ba fe se wa n’ibi

     K'iro yi pe, 'Tire l’awa

     Tu etan ese ka.


4.  Gbati Esu ba ntafa re 

     S’ori ailera wa

     K’iro yi pe, ‘Tire l’awa 

     Ma je ki o re wa.


5.  Tire n'igb’awa l’Omode 

     Tire n'igba a ndagba 

     Tire n'igb'a ba darugbo 

     Ti aiye wa mbuse.


6.  Tire titi lai l‘awa se

     A f' ara wa fun O

     Tlti aiye ainipekun 

     Amin, beni k'o ri.  Amin

English »

Update Hymn