HYMN 632

C.M.S 497 t.H.C 324 8s 7s. (FE 658)
"Wa sodo mi" - Isa. 55:3



1.  EMI o lo sodo Jesu 

     Eni npe mi pe ki nwa 

     Enit’ o se Olugbala 

     Fun elese bi emi.


2.  Emi o lo sodo Jesu 

     Irira at’ibinu

     Ika at'ise t'o buru 

     T’enia nse, On ko ni.


3.  Emi o lo sodo Jesu 

     O dun mo mi ki nse be 

     Tal’ o fe mi bi ti Jesu 

     Eniti o gba ni la?


4.  Emi o lo sodo Jesu 

     Jesu t'o se Ore wa

     Anu wa ninu Re pupo 

     Fun elese bi emi.  Amin

English »

Update Hymn