t. H.C 465 7s (FE 648) “E ma si de da won lekun" - Marku 10:14 1. JESU Baba omode Ase re ni awa nse A m’omo yi wa ‘do Re Ki iwo so di Tire. 2. Ninu ese ni a bi We kuro nin’ese re Eje re ni a fi ra K'opin ninu Ebun Re. Amin