C.M.S 454 H.C 2nd Ed 329 t. S. 668. S.M (FE 646) "Enikeni ti o gba okan ninu awon omode wonyi li oruko Mi, o gba mi" - Marku 9:37 1. EMI Olorun wa, Baptis awon wonyi Ba won da majemu mimo We won kuro l'ese. 2. F’opa esu tutu We won n'nu eje Re Baba, Omo, Emi Mimo So nwon di Omo Re. Amin