C.M.S 448 t.H.C 34 C.M (FE 645) “Eje Jesu Kristi omo re ni nwe wa nu kuro ninu ese wa gbogbo" - 1Joh. 1:7 1. NIHINYI n’isimi gbe wa Niha re ti eje nsan Eyi nikan n’ireti mi Pe Jesu ku fun mi. 2. Olugbala Olorun mi Orisun f‘ese mi Ma f‘eje re won mi titi K’emi le di mimo. 3. We mi, si se mi ni Tire We mi, si je temi We mi, ki s‘ese mi nikan Owo at’okan mi. 4. Ma sise lokan mi, Jesu Titi gbagbo y'o pin Tit’ ireti y‘o fi dopin T'okan mi yio Simi. Amin