HYMN 616
(FE 642)
"Adaba mimo si ba le ori
re" - Matt. 3:16
1. JESU nlo sinu odo Jordan - 3ce
Lodo Johanu Baptist.
Egbe: A nlo sodo Jordan
Pelu Olugbala wa
A nlo soda Jordan!
Odo iwenumo.
2. Ka to le d’ade, a o ma korin - 3ce
Orin ife mimo.
Egbe: A nlo sodo Jordan...
3. Jesu yio gbade f'omo Re - 3ce
F'awon ayanfe Re.
Egbe: A nlo sodo Jordan...
4. Adaba, mimo sokale - 3ce
S'or'Olugbala wa.
Egbe: A nlo sodo Jordan...
5. A gbohun kan lat'orun wa - 3ce
Eyi l'ayanfe Mi.
Egbe: A nlo sodo Jordan...
6. Ema gbo Tire titi aiye, - 3ce
Odo Iwenumo.
Egbe: A nlo sodo Jordan...
7. Jesu Oluwa ti d'odo na - 3ce
Odo Iwenumo.
Egbe: A nlo sodo Jordan...
8. Gbogbo elese e wa kalo - 3ce
Sinu odo Jordan.
Egbe: A nlo sodo Jordan...
9. Kerub' Serafu e wa kalo - 3ce
Sod' Olugbala wa.
Egbe: A nlo sodo Jordan...
10. Ade iye yio je ti wa - 3ce
Bi a ba gba Jesu gbo.
Egbe: A nlo sodo Jordan
Pelu Olugbala wa
A nlo soda Jordan!
Odo iwenumo. Amin
English »Update Hymn