C.M.S 406 t. H.C 18 C.M (FE 630) 'Gbogbo eniti ongbe ngbe, e wa sibi omi" - Isa. 55:1 1. ENYIN t’ongbe ngbe e wa mu Omi iye ti nsan Lati orisun ti Jesu Lai sanwo l’awa mbu. 2. Wo! b’o ti pe to t'e ti nmu Ninu nkan eke T'e nl'agbara at’ogun nyin Ninu nkan t'o nsegbe. 3. Jesu wipe, isura mi Ko lopin titi lai Yio f ‘ilera lailai fun Awon t'o gbo Tire. Amin