ORO ALAFIA Tune: YMHB 793 - 6s 8.4 1. ORO Alafia La fi sin nyin ara K’alafia bi odo nla Ma ba nyin gbe. 2. N'nu oro adura Af’ awon ara wa Le ise Oluwa lowo Ore toto. 3. Oro ife didun L'a fi p'odigbose Ife wa ati t'Olorun Y‘o ba won gbe. 4. Oro'gbagbo lile Ni igbekele wa Pe, Oluwa y’o se ranwo Nigba gbogbo. 5. Oro'reti didun Y’o mu Ipinya wa dun Y‘o so ayo t’o le dun ju Ayo t' aiye. 6. Odigbose, ara N’ife at’igbagbo Tit' ao fi tun pade loke N'ile wa orun. Amin