HYMN 572

t.G.B 466 (FE 599)
"Iwo ba wa kalo" - Num. 10:29



1.  ENYIN ero nibo l’e nlo 

     T‘enyin t’asia lowo?

     Awa nlo s’orere aiye 

     Lati kede oro na.

Egbe: Awa Om'egbe Serafu 

          Ti Olorun tun gbe dide 

          Awa si njo, awa si nyo)
 
          Fun ore t'a gba lofe). 2ce


2.  Enyin agba, enyin ewe

     E ba wa ko orin na

     At’okunrin at’obinrin

     K’a jo jumo juba Re. 

Egbe: Awa Om'egbe Serafu...


3.  Enyin Egbe Onigbagbo 

     T’o wa ni gbogbo aiye

     Ka fi keta gbogbo sile 

     K'a f'omonikeji wa. 

Egbe: Awa Om'egbe Serafu...


4.  E wa jumo k’egbe lo

     Wa si egbe Serafu 

     Wa ma kalo, wa ma kalo 

     Gbogbo wa ni Jesu npe.

Egbe: Awa Om'egbe Serafu 

          Ti Olorun tun gbe dide 

          Awa si njo, awa si nyo
 
          Fun ore t'a gba lofe.

          Awa si njo, awa si nyo
 
          Fun ore t'a gba lofe.  Amin

English »

Update Hymn