HYMN 568
H.C 164 t.H.C 323 C.Ms (FE 595)
“Enoku si ba Olorun rin"- Gen.5:24
1. EMI ‘ba le f’iwa pele
Ba Olorun mi rin
Ki mni imole ti nto mi
Sodo Odagutan!
2. Ibukun ti mo ni ha da
Gba mo ko mo Jesu?
Itura okan na ha da
T'oro Kristi fun mi?
3. Alafia mi nigbana
Ranti re ti dun to!
Sugbon nwon ti b’afo sile
Ti aiye ko le di.
4. Pada, Emi Mimo, pada
Ojise itunu
Mo ko ese t‘o bi O n’nu
T’o le O lokan mi.
5. Osa ti mo fe rekoja
Ohun t’o wu k’o je
Ba mi yo kuro lokan mi
Ki nle sin 'Wo nikan.
6. Bayi ni ngo b’Olorun rin
Ara o ro mi wo!
Mole orun y‘o ma to mi
Sodo Odagutan. Amin
English »Update Hymn