H.C. 363 8s 7s (FE 588) “Apoti eri Oluwa siwaju won" - Num.10:33 1. MA toju wa Baba Orun Larin ‘damu aiye yi Pa wa mo k‘o si ma bo wa A ko n’iranwo miran Sugbon gbogbo ‘bukun I'a ni B’Olorun je baba wa. 2. Olugbala, dariji wa lwo sa m'ailera wa Wo ti rin aiye saju wa Wo ti mo ‘se inu re B’en' ikanu at’alare L’O ti la ‘ginju yi ja. 3. Emi Olorun, sokale F’ayo orun k‘okan wa K’ife dapo mo iya wa At’adun ti ki sun ni B'a ba pese fun wa bayi Kil' o le mi simi wa? Amin