HYMN 560

H.C 370 6s. 4s (FE 587) 
"Alejo ni ile ajeji”
- Eks.2:22



1.  NIHIN mo j'alejo 
 
     Orun n’ile

     Atipo ni mo nse 

    Orun n’ile,

    Ewu on ‘banuje, 

    Wa yi mi kakiri 

    Orun ni ilu mi 

    Orun n’ile.


2.  B'iji ba tile nja 

     Orun n’ile 

     Kukuru l’ajo mi 

     Orun n’ile

     Iji lile ti nja

     Fe rekoja lo na 

     Ngo sa de le dandan 

     Orun n’ile.


3.  Lodo Ol‘ugbala

     Orun n'ile

     A o se mi logo

     Orun n'ile

     Nib' awon mimo wa 

     Lehin ‘rin-ajo won 

     Ti nwon ni simi won 

    Nibe n'ile.


4.  Nje nki o kun, tori 

     Orun n’ile

     Ohun t’o wu ki nri 

     Orun n’ile

     Ngo sa duro dandan 

     L’otun Oluwa mi 

     Orun ni ilu mi 

     Orun n'ile.  Amin

English »

Update Hymn