HYMN 552

C.M.S 572 H.C 589 L.M (FE 579)
“Olorun igbala wa, eniti ise igbekele 
gbgogbo opin ile aiye, ati okun ti o 
jina rere" - Ps.65:5



1.  BABA, jowo gb’adura wa 

     Bi a ti nlo loju omi

     Iwo maje ebute wa 

     At’ile wa loju omi.


2.  Jesu Olugbala ‘Wo ti 

     O ti mu ‘ji dake roro 

     Ma je ayo fun asofo 

     Fi simi ‘fokan aibale.


3.  Wo Emi Mimo, Eniti 

     O rababa loju omi 

     Pase ‘bukun lakoko yi 

     Fi ipa Re mu wa soji.


4.  Wo Olorun Metalokan

     Ti awa nsin, ti awa mbo 

     Ma se’bi sadi wa l’aiye 

     Ati ayo wa li orun.  Amin

English »

Update Hymn