C.M.S 452 H.C 456 t. H.C 173 L.M (FE 578) "Baptist won l'oruko Baba ati niti Omo ati niti Emi Mimo" - Matt.28:19 1. WA Emi, Mimo sokale Onibaptisi okan wa M’edidi majemu Re wa K‘o si se eri omi yi. 2. Tu agbara nla Re jade K'o o si won eje etutu Ki Baba, Omo at‘ Emi Jo so won d'omo Olorun. Amin