HYMN 550

(FE 577)




1.  ENYIN ara ati ojulumo

     E wa wole ki le ayo to kun

     Gbogbo aiye ni Jesu npe tantan 

     Wa wo oko igbala yi ki o to kun.

Egbe:  Yara wa, wa wole)

           Jesu lo npe nyin tantan). 3ce

           Ki oko Noah ikehin 

           yi ko to kun tan.

  
2.  Gbogbo Egbe at’Ijo Olorun 

     Keferi ati Imale ilu

     Gbogbo aiye ni Jesu npe tantan 

     Wa wo oko igbala yi ki o to kun. 

Egbe:  Yara wa, wa wole...


3.  Ijo Afrika wa ba wa josin 

     Ati gbogbo ljo Omo ‘bile 

     Jesu Kristi’ lo wipe ki e wa

     Wa wo oko igbala yi ki o to kun. 

Egbe:  Yara wa, wa wole...


4.  Olorun Shedrack lo npe nyin tantan 

     Olorun Mesak lo npe nyin tantan 

     Olorun Abednego lo npe nyin

     Wa wo oko igbala yi ki o to kun. 

Egbe:  Yara wa, wa wole...


5.  Olorun Abram lo npe nyin tantan 

     Olorun Isaac lo npe yin tantan 

     Olorun Jacob lo npe nyin tantan 

     Wa wo oko igbala yi ki o to kun. 

Egbe:  Yara wa, wa wole...


6.  Olorun Dafidi lo npe nyin tantan 

     Olorun Daniel lo npe nyin tantan 

     Olorun Batimeu lo npe nyin tantan 

     Wa wo oko igbala yi ki o to kun. 

Egbe:  Yara wa, wa wole...


7.  Olorun Mary lo npe nyin tantan 

     Olorun Martha lo npe nyin tantan 

     Olorun Esther lo npe nyin tantan 

     Wa wo oko igbala yi ki o to kun. 

Egbe:  Yara wa, wa wole...


8.  Kerubu ati Serafu lo npe nyin 

     Eni Mime, Israeli lo npe nyin 

     Gbogbo Ogun Orun lo ni k'e wa 

     Wa wo oko igbala yi ki o to kun. 

Egbe:  Yara wa, wa wole)

           Jesu lo npe nyin tantan). 3ce

           Ki oko Noah ikehin 

           yi ko to kun tan.  Amin


English »

Update Hymn