H.C. 411 C.M. (FE 569) “Emi li ona, otito ati iye" - John14:6 1. IWO l’Ona-odo re ni Awa o ma sa bo Awon t’o nsaferi Baba Yio wa s’odo Re. 2. Iwo l’Oto-oro Tire L’o le f’ogbon fun wa Iwo nikan l’ o le ko wa T’O si le we okan. 3. lwo n’Iye: iboji Re Fi agbara Re han Awon t‘o gbeke won le O Nwon bo lowo iku. 4. lwo l'Ona, Oto, Iye Jek’a mo ona Re K'a mo otito at’lye T’ayo re ko l’opin. Amin