HYMN 538

H.C. 341 L.M (FE 564)
“Bere ohun ti Emi o fi fun o” 1Oba.3:5



1.  OLUWA, Iwo ha wipe

     Ki mbere ohun ti mo nfe? 

     Jo, jeki mbo lowo ebi

     Ati low’ese on Esu.


2.  Jo, fi ara Re han fun mi 

     Si jeki nru aworan Re 

     Te ite Re si okan mi 

     Si ma nikan joba nibe.


3.  Jeki nmo p’O dariji mi 

     Ki ayo Re s’agbara mi

     Ki nmo giga, ibu, jijin 

     Ati gigun ife nla Re.


4.  Eyi nikan ni ebe mi

     Eyit’ O ku di owo Re

     lye, iku, aini, oro

     Ko je nkan, b’O ba je temi.  Amin

English »

Update Hymn