HYMN 537

C.M.S 349 H.C 11s (FE 563) 
“So mi di aye" - Ps. 119:25



1.  Fun mi n’iwa mimo 

     Igbona okan

     Suru ninu iya, aro fun ese 

     Igbagbo n’nu Jesu:

     ki nmo ‘toju Re;

     Ayo n’nu isin Re;

    emi adura.


2.  Fun mi l’okan ope,

     igbkele Krist’

     Itara f’ogo Re ‘reti n’nu Oro Re 

     Ekun fun iya Re; ‘rora f’ogbe Re 

     Irele n’nu ‘danwo;

     iyin fun ‘ranwo.


3.  Fun mi n’iwa funfun 

     fun ni n'isegun

     We abawon mi nu'fa 

     ‘fe mi s’orun

     Mu mi ye ‘joba Re, ki nwulo fun O 

     Ki nj’alabukun fun, ki ndabi Jesu. Amin

English »

Update Hymn