t.H.C 18 C.M. (FE 562) "Kiyesi o ti dara o si ti dun“ - Ps.113:1 1. WO! b’o ti dun to lati ri Awon ara at'ore Ara ti okan won s’okan L’egbe ide mimo. 2. Gba isan ‘fe t'odo Krist sun O san s'okan gbogbo Alafia Olodumare Dabobo gbogbo re. 3. O dabi ororo didun Ni irugbon Aaron Kikan re m'aso re run ‘re O san s’agbada re. 4. O dara b‘iri owuro To nse soke Sion Nibit Olorun f‘ogo han T'o m’ore-ofe han. Amin