HYMN 530

H.C 478 8s 4s (FE 556) 
"Ore kan mbe ti o fi ara mo mi 
ji arakunrin Io" - Owe 18:24



1.  ENIKAN mbe t’o feran wa, 

     A! O fe wa!

     Ife re ju ti yekan lo

     A! O fe wa

     Ore aiye nko wa sile 

     B’oni dun ola le koro 

     Sugbon ore yi ko ntan ni 

     A! O fe wa!


2.  lye ni fun we b’a ba mo 

     A! O fe wa!

     Ro, b’a ti je n’igbese to 

     A! O fe wa!

     Eje Re lo si fi ‘ra wa 

     Nin’aginju l’o wa wa ri 

     O si mu wa wa s’agbo Re 

     A! O fe wa!


3.  Ore ododo ni Jesu

     A! O fe wa!

     O fe lati ma bukun wa 

     A! O fe wa!

    Okan wa fe gbo ohun Re 

    Okan wa fe lati sunmo 

    On na ko si ni tan wa je 

    A! O fe wa!


4.  Loko Re la nri dariji 

     A! O fe wa!

    On o fe ota wa sehin 

    A! O fe wa!

   On o le ota wa sehin 

    A! O fe wa!

    On o pese bukun fun wa 

    lre l'a o ma ri titi

    On o fi mu wa lo s’Ogo 

    A! O fe wa!  Amin

English »

Update Hymn