C.M.S 346 O. t.H.C 320 C.M (FE 553) "E ma ru eru omonikeji nyin" - Gal. 6:2 1. ALABUKUN ni fun ife Ti ki oje k’a ya Bi ara wa jina s’ara Okun wa wa l’okan. 2. Da opo Emi s‘ori wa Ona t’Ola l’a nto Nipa ti Jesu l’a si nrin Iyin Re l'a nfi han. 3. Awa ba ma rin l‘ona Re K’a ma sin m’ohun kan K’a ma fe ‘hun kan, bikose Jesu t’a pa fun wa. 4. K'a sunmo O girigiri Ati si ona Re K‘a ma r’ore gba lodo Re Ekun ore-ofe. Amin