HYMN 526

O.t.H.C. 60 7s (FE 551)
"Ki ife ara ki o pe titi‘"
 - Heb. 13:1



1.  JESU, Iwo ni a nwo 

     K’a repo l‘oruko Re

     Alade alaiia

     Mu k‘ija tan l’arin wa.


2.  Nipa ilaja Tire

     Mu idugbolu kuro 

     Jek'a dapo si okan 

     F'itegun Re sarin wa.


3.  Jek'a wa ni okan kan 

     K'a se anu at‘ore 

     K'a tutu l'ero l‘okan 

     Gege bi Oluwa wa.


4.  K‘a s‘aniyan ara wa 

     K‘a ma reru ara wa 

     K‘a f‘apere fun ljo 

     B'Olugbagbo ti gbe po.


5.  K‘a kuro ni ibinu

     K‘a simi le Olorun

     K‘a so ti ibu ife

     At‘iwa giga mimo.  Amin

English »

Update Hymn