HYMN 521

H.C 319 7s (FE 546)
"Iwo fe mi bi?" - John 21:16



1.  OKAN mi, Oluwa ni 

     Jesu re ni, gboro Re 

     Jesu nso, O mba o so 

     Pe, elese ‘Wo fe mi?


2.  Gbat‘ a de o, Mo da o

     O gb’ogbe, Mo wo o san 

     Gb’ o sako, Mo mu o bo 

     Mo s’okun re d'imole.


3.  Kike iya ha le mo

     Si omo re ti o bi? 

     Lotito o le gbagbe 

     Sugbon Em’o ranti re.


4.  Ife t'Emi ki ye lai 

     O ga rekoja orun 

     O si jin ju okun lo 

     Ife alailegbe ni.


5.  Wo fere r’ogo Mi na 

     Gb’ise ore-ofe tan 

     Wo o ba Mi gunwa po 

     Wi, elese, wo fe mi?


6.  Olori aroye mi

     Ni pe ife mi tutu

     Sugbon mo fe O Jesu

     A! mba le fe O ju yi!.  Amin

English »

Update Hymn