HYMN 50
(FE67)
Tune: Alejo kan nkan ‘lekun G.B
190 “Baba gbo, Baba dariji”
1. BABA Oludariji, Dariji
Gbogbo awa omo Re, Dariji,
Awa Egbe Serafu,
Ati Egbe Kerubu
Ati npafo ninu ese, Dariji.
2. JESU OLUGBALA WA Dariji
OLURADAPA Eda Dariji,
Wo to mbebe f‘ota Re
L'origi Agbelebu
Wipe fiji won BABA Dariji.
3. EMI OLUTUNU wa, Daniji
Gbogbo ebi ese wa, Dariji
Gba wa lojo idamu
Se Oluranlowo wa,
Mase jeki a bohun Dariji.
4. METALOKAN jowo wa Dariji
Omode ati Agba Dariji,
JAH JEHOVAH RAMMAH
‘Wo l’Oba Oniyonu,
Dariji ‘se owo Re Dariji. Amin
English »Update Hymn