C.M.S 7, H.C. t.H.C 258 S.M. (FE 22) "Lale loro ati losan li emi o ma gbadura" Ps. 55:7 1. WA s'adura oro Kunle k'a gbadura; Adura ni opa Kristiani, Lati b'Olorun rin. 2. Losan, wole labe Apat' aiyeraiye; Itura ojiji Re dun, Nigbat' orun ba mu. 3. Je ki gbogbo ile, Wa gbadura l'ale Ki ile wa di t'Olorun, Ati 'bode orun. 4. Nigbati od'oganjo Jek'a wi l'emi, pe Mo sun, sugbon okan mi ji Lati ba O sona. Amin