C.M.S 584 t.H.C 318 C.M (FE 522) "Eniti o si tan gbogbo re" - Ps.103:3 1. ENIT‘O la ju afoju Ti O mu ope gbon At’enit'O da imole Fun eni okunkun. 2. Enit'O le fi agbara F’awon olokunrun Ti O si fi emi iye Fun awon t'o ti ku. 3. Eni fi ‘dasile f'okan T'O gb’eni subu nde T’O si pa ibanuje da S’orin pelu iyin. 4. Wo Onisegun okan mi Si O l’awa nkorin Titi aiye o fi d’opin Tire l’ope o se. Amin