HYMN 495

C.M.S 506 H.C 2nd Ed
457 t.H.C 528 L.M (FE 521)
“Emi fi ohun mi kigbe si Olorun
O si fe eti si mi“ - Ps.77:1



1.  OLORUN mi, ‘Wo l‘emi o pe

     Ara nni mi, gbo igbe mi

    Gba'san omi ba bori mi 

    Ma je k’okan mi fa sehin.


2.  lwo Ore alailera

     Tani mba s’aroye mi fun 

     Bikose ‘Wo nikansoso 

     T'o npe otosi wodo Re?


3.  Tal'o sokun to O lasan ri? 

     Wo koi gbagbe enikan ri 

     Se lwo ni O ti so pe 

     Enikan k' yo wa O lasan?


4.  Eyi ’ba je ‘banuje mi

     Pa, O ko ndahun adura 

     Sugbon ‘Wo ti ngbo adura 

     lwo l‘O nse iranwo mi.


5.  Mo mo pe alaini l’emi

     Olorun Ko ni gbagbe mi

     Eniti Jesu mbebe fun

     O bo Iowo gbogbo ‘yonu.  Amin
 

English »

Update Hymn