HYMN 491

8s 7s (FE 517)
Tune: Wo Oluwa l'awosanma



1.  EMI iwosan sokale wa

     Wa pelu agbara Re 

     Wa pelu ogo at'Ola Re 

     Wa pelu Ase Nla Re

Egbe:  Wo iranse re san

           Fun ni alafia 

           Fun ni ara lile

           K'emi re s'owon loju Re.


2.  Emi iwosan sokale wa 

     Dar'ese omo re ji

     Ki o ya omo Re si mimo 

     Ki ebe wa je itewogba. 

Egbe:  Wo iranse re san...


3.  Emi ti nji oku did e 

     Emi to ba Elisah sise 

     Emi to ba Elijah sise 

     Sokale l'agbara Re e. 

Egbe:  Wo iranse re san...


4.  Emi ti n gbe ro dide

     Emi to ba Peteru sise 

     Emi to ba Johanu sise 

     Sokale l'agbara Re e. 

Egbe:  Wo iranse re san...


5.  Emi ti nso oku d'alaye

     Emi to ba Mose sise 

     Orimolade Baba wa

     Wa pelu Ase Nla Re. 

Egbe:  Wo iranse re san...


6.  Emi to nla oju afoju

     Emi to nwo alarun san 

     Emi ti ns‘adete di mimo 

     Emi ti nsise iyanu nla. 

Egbe:  Wo iranse re san...


7.  Emi ti nwo asinwin san,

     Emi ti nporo ofa ota

     Emi ti nsegun agbara aje 

     Emi Ito Alafia.

Egbe:  Wo iranse re san

           Fun ni alafia 

           Fun ni ara lile

           K'emi re s'owon loju Re.  Amin

English »

Update Hymn