HYMN 486

C.M.S 428 H.C 431 S.M (FE 512)
"Bi olukuluku ti ri ebun gba" - 1Peter. 4:10



1.  OHUN t'a fi fun O

     Tire ni Oluwa

     Gbogbo ohun ti a si ni 

     Owo Re loti wa.


2.  Jek' a gba ebun Re

     Bi iriju rere

     Bi O si ti mbukun wa to

     Be l'a o fi fun O.


3.  Opo ni ise nse

     Ti nson ko r'onje je 

     Opo l'o si ti sako lo

     Kuro l'agbo Jesu.


4.  K'a ma tu ni ninu 

     K'a ma re ni l'ekun

     K'a ma bo alainibaba

     N'ise t'a ba ma se.


5.  K’a tu onde siIe

     K‘a f‘ona iye han 

     K‘a ko ni Iona OIorun 

     B’iwa Krsisti lo ri.


6.  A gba oro Re gbo

     Busi igbagbo wa

     Ohun t’a se fun eni Re 

     Jesu, a se fun O.  Amin

English »

Update Hymn