HYMN 482
S.S. 393 (FE 508)
"Anu nsan pupo, Iwo Oluwa po"
- Ps.86:5
1. OGO fun Jesu f'anu Re lofe
Anu lofe, anu lofe,
Elese anu nsan, fun o lofe
Anu nsan pupo lofe
Bi iwo ba fe lati gba a gbo
Anu lofe, anu lofe
Iwo yio r'iye ainipekun gba
Anu nsan pupo lofe.
Egbe: Jesu Olugbala nwa o kiri
Nwa o kiri, nwa o kiri
T'anu -t'anu t'ife lo fi npe o,
O npe o, O nwa o kiri.
2. Ese to nkiri lokiti ese?
Anu lofe, anu lofe
Emi npe o jeje wipe wa 'le
Anu nsan pupo lofe
O nwa n'okun bi? A! wa si 'mole
Anu lofe, anu lofe
Jesu nduro yio gba o lale yi
Anu nsan pupo lofe.
Egbe: Jesu Olugbala nwa o kiri...
3. Ro ti ore, suru, ati ife re
Anu lofe, anu lofe
O bebe fun o lodo Baba loke
Anu nsan pupo lofe
Wa ronupiwada fun lokan re
Anu lofe, anu lofe
Ma banuje sugbon wa b'o ti ri
Anu nsan pupo lofe.
Egbe: Jesu Olugbala nwa o kiri...
4. Nje anu wa fun gbogb' eni gbagbo
Anu lofe, anu lofe
Wa k'o si gba 'bukun nisisiyi
Anu nsan pupo lofe
esu nduro, A! gbo b'O ti nkede
Anu lofe, anu lofe
Ro mo 'leri Re 'gba Oko Re gbo
Anu nsan pupo lofe.
Egbe: Jesu Olugbala nwa o kiri
Nwa o kiri, nwa o kiri
T'anu -t'anu t'ife lo fi npe o,
O npe o, O nwa o kiri. Amin
English »Update Hymn