HYMN 48
SS 379 (FE 65)
"E we, ki e mo” - Isa 1:16
1. OTITO Jesu f ’agbara ‘wenumo
A we o ninu eje Odagutan
Iwo ha gbekele ore-ofe Re,
A we o ninu eje Odagutan.
Egbe: Awe o, ninu eje
Ninu eje Odagutan fun okan
Asa re ha funfun o si mo laulau
Awe o ninu eje Odagutan.
2. O mba Olugbala rin lojo jumo
A we o ninu eje Odagutan
O simi le Eniti a kan mo’gi
A we o ninu eje Odagutan.
Egbe: Awe o, ninu eje...
3. Aso re funfun lati pade Oluwa,
O mo lau ninu eje Odagutan
Okan re mura fun ‘le didan loke
K’a we o ninu eje Odagutan.
Egbe: Awe o, ninu eje...
4. Bo ewu eri ese si apa kan
Ko si we ninu eje Odagutan
Isun kan nsan fun gbogbo okan aimo,
Jo lo we ninu eje Odagutan.
Egbe: Awe o, ninu eje... Amin
English »Update Hymn