HYMN 476
(FE 502) Tune: "Egbe Aladura mura"
“Oluwa yara gba wa" - Ps.70:1
1. OLUWA Olorun gba wa, lowo iku ojiji
Olorun Olugbala wa iwo l’awa gbekele
Oluwa dabobo wa lowo aje. at’oso
Ise po t’awa yio se nitorina da wa si.
Egbe: Da wa si, da wa si ) 2ce
Ise po t'awa yio se
Nitorina da wa si.
2. Olorun Olodumare, gba wa
low’ ajak’arun
Ma je ki emi buburu, le wole
to Serafu
Oluwa dabobo wa, lowo aje, at’oso
Ise po t’aw yio se, nitorina da wa si.
Egbe: Da wa si, da wa si...
3. Emi Mimo ko pelu wa l’okunrin at’obinrin
Ka le je ti Kristi Oluwa, larin odun t’a wa yi
Oluwa dabobo wa, lowo aje, at‘oso
Ise po t’awa yio se, nitorina da wa si.
Egbe: Da wa si, da wa si ) 2ce
Ise po t'awa yio se
Nitorina da wa si. Amin
English »Update Hymn