S.S & 692.7s. 6s (FE 498) 1. GBEKELE onigbagbo Bi ‘ja na tile pe Iwo ni yio sa segun Baba y’o ja fun o. Egbe: Sa gbekele! B’okunkun tile su Sa gbekele! Ile fere mo na. 2. Gbekele larin ewu Danwo nla wa n‘tosi Larin wahala aiye Baba ma s’amona. Egbe: Sa gbekele!... 3. Jesu to lati gba wa Ore toto l’Oje Gbekele, onigbagbo Sa gbekele dopin. Egbe: Sa gbekele! B’okunkun tile su Sa gbekele! Ile fere mo na. Amin