HYMN 466

H.C 300 8s 4s (FE 491) 
“Alafia ki o wa bi Alafia ni”
- 2Kings. 4:26



1.  NIPA ife Olugbala

     Ki y’o si nkan

     Ojurere Re ki pada

     Ki y’o si nkan 

     Owo n l’eje t’o wo wa san 

     Pipe l’edidi or’ofe

     Agbara l’owo o gba ni 

     Ko le si nkan.


2.  Bi a wa ninu iponju

     Ki y’o si nkan 

     Igbala kikun ni tiwa

     Ki y’o si nkan 

     Igbekele Olorun dun 

     Gbigbe inu Krist’ l’ere 

     Emi si nso wa di mimo 

     Ko le si nkan.


3.  Ojo ola yio dara

     Ki y’o si nkan

     Gbagbo le korin n’iponju

     Ki y’o si nkan

     A gbekele ‘fe Baba wa

     Jesu nfun wa l’ohun gbogbo 

     Ni yiye tabi ni kiku 

     Ko le si bkan.  Amin

English »

Update Hymn