HYMN 457

H.C 304 6.10s (FE 482)
"Oluwa ni ipin mi n okan mi wi"
 - Ekun. 3:34



1.  LALA mi po, nko ni ‘simi laiye 

     Mo rin jinna, nko r‘ibugbe laiye 

     Nikehin mo wa won laiya Eni 

     T’o n’owo Re, t'O si npe alare 

     Lodo Re, mo r’ile at’isimi 

     Mo si di Tire, On si di temi.


2.  Ire ti mo ni, lat’odo Re ni 

     B’ibi ba de, o je b’o ti fe ni

     B’On j’ore, mi mo la bi nko ri je 

     L’aisi Re, mo tosi bi mo l’oro

     Ayida le de, ere tab’ofo

     O dun mo mi, bi 'm ba sa je Tire.


3.  B’ayida de, mo mo ‐ on ki yida 

     Orun ogo ti ki ku, ti ki wo 

     O nrin lor’awosanma at’iji

     O ntanmole s'okukun enia Re 

     Gbogbo nkan le lo, ko ba mi n’nu je 

     Bi m’ba je Tire, ti On je temi.


4.  A! laiye, nko mo idaji ‘fe Re; 

     Labo ni mo nri, labo ni mo nsin 

     ‘Gba mo ba f’oju kan loke lohun 

     Ngo feran Re po, ngo si yin jojo 

     Ngo wi larin egbe orin orun

     Bi mo ti je Tire, t’On je temi.  Amin

English »

Update Hymn