HYMN 449

K.III. t.H.C (FE 474) S.M 
“Ma beru, emi wa pelu re” 
- Gen. 26:24



1.  F’ERU re f’afefe

     N’ireti ma foiya 

     Olorun gbo ‘mikanle re

     Yio gb’ori re ga.


2.  N’irumi at’iji

     Y’o s’ona re fefe 

     Duro de igba Re, oru 

     Y’o pin s’ojo ayo.


3.  Iwo r’ailera wa

     Inu wa n’iwo mo 

     Gbe owo t’o re si oke 

     M’ekun ailera le.


4.  K’awa, n'iyen n’iku 

     So, oro Re tantan

     K’a so tit’ opin emi wa 

     Ife, itoju Re.  Amin

English »

Update Hymn