HYMN 448
(FE 473)
"lwo ki yio beru nitori eru oru"
- Ps. 91:5
1. ENYIN Omo Egbe Kerubu
Ma beru, ma sojo
Oluwa l’o n ran wa n’ise
Awa ki yio beru.
Egbe: Baiye nsata pelu Esu
Eke ni won, nwon nse lasan
B’aiye nsatan, pelu esu
Eke ni nwon, nwon nse lasan.
2. Enyin Omo Egbe Serafu
Ma je k’oju ti nyin
lse Oluwa l’a wa nje
Awa ki yio tiju.
Egbe: Baiye nsata pelu Esu...
3. Enyin Egbe Aladura
E mura s‘ise nyin
Gbogbo ise nyin ti e nse
Okan ko lo lasan.
Egbe: Baiye nsata pelu Esu...
4. Enyin Omo Egbe Bibeli
E mura s’adura
K’Olorun la oju emi nyin
Lati rohun ijinle.
Egbe: Baiye nsata pelu Esu...
5. Enyin Omo Egbe Akorin
E tun ohun nyin se,
Orin l’awa yio ko lorun
A ko n‘ise miran.
Egbe: Baiye nsata pelu Esu...
6. E’ogo fun Metalokan
Baba Omo, Emi
Titi aiye ainipekun
Amin! beni ki o ri.
Egbe: Baiye nsata pelu Esu
Eke ni won, nwon nse lasan
B’aiye nsatan, pelu esu
Eke ni nwon, nwon nse lasan. Amin
English »Update Hymn