HYMN 447

H.C. 292. t.H.C 483
(2nd Tune) C.M. (FE 471)
"Oluwa ni yio ma se Olorun mi"
- Gen. 28:21



1.  BABA, b'ife Re ni, lati 

     Du mi l’ohun aiye 

     Sa je ki adura mi yi 

     Goke de ite re.


2.  F'okan tutu, t’ope fun mi 

     Gba mi lowo kikun

     Fun mi n‘ibukun or-ofe 

     Si je ki nwa fun O.


3.  K'ero yi pe, Wo ni temi 

     Ma ba mi lo l'aiye

     Pelu mi Iona ajo mi

     Si ba mi d‘opin re.  Amin

English »

Update Hymn