HYMN 445

t.H.C 153 8s (FE 469)
“Tani Olorun bi Iwo, ti o ndari aise
dede ji" - Mik. 7:18



1.  OLORUN Iyanu ona kan 

     Ti o da bi Tire ko si 

     Gbogb’ogo ore-ofe Re 

     L’o farahan bi Olorun.

Egbe:  Tal’Olorun ti ndariji 

           Ore tal’o po bi Tire?


2.  N’iyanu at’ayo l’agba 

     Idariji Olorun wa 

     ‘Dariji f’ese t’o tobi 

     T’a f’eje Jesu s’edidi.

Egbe:  Tal’Olorun ti ndariji...

 
3.  Je ki ore-ofe re yi 

     Ife iyanu nla Re yi

     K’o f’iyin kun gbogbo aiye

     Pelu egbe Angel l’oke.

Egbe:  Tal’Olorun ti ndariji 

           Ore tal’o po bi Tire?  Amin

English »

Update Hymn