HYMN 432
H.C 272 10s (FE 456)
"O ye ki enia ma gbadura nigba
gbogbo, ati laise are" - Luku 18:1
1. MA gbadura, Emi mbebe N’nu re
Fun gbogbo aini re igbagbogbo.
2. Ma gbadura, labe eru ese
Adura nri eje Jesu ti nsan.
3. Ma ghadura, b‘are tile mu O
Adura ngbe wa s'eba ‘te, Baba.
4. Ma gbadura, n’nu wahala aiye,
Adura l'o nfun okan n‘isimi.
5. Ma ghadura, b'ayo ba yi o ka
Adura nlu harp, o nkorin Angel’
6. Ma ghadura, b'awon t'o feran ku
Adura mba won mu omi iye
7. Gbogb'ohun aiye y'o b’ aiye koja
Adura wa titi: ma gbadura. Amin
English »Update Hymn