C.M.S 547 t.H.C 299 C.M. (FE 453) "Oro mi ki yio pada sodo mi lofo" - Isa. 55:11 1. OLORUN, a so oro Re Bi 'rugbin l‘or‘ile Je k'iri orun se sile K'o mu ipa re wa. 2. K'ota Kristi on enia Muse se sa 'rugbin na K’o f'irin mule l'okan wa K'o dagba ni ife. 3. Ma je ki aniyan aiye Bi oro on ayo Tabi ijona, on iji Run lrugbin orun. Amin