C.M.S 532 t.H.C 500 C.M (FE 452) “Iwo ni se ibujoko apata mi" - Ps.71:3 1. OLUWA, 'Wo ki o si gba Eni osi bi emi K’emi le sunmo ite Re Ki nke Abba, Baba. 2. Jesu, jowo fi oro Re, S'okunkun mi d’osan Ki gbogbo ayo tun pada Ti mo f'ese gbon nu. 3. Oluwa, mo f’iyanu sin, Ore Re tobi ju Pa mi mo ninu ife Re K'emi ma d’ese mo. Amin