HYMN 428

C.M.S 535 C.H. 411 t.S. 672. S.M
(FE 451)
"E je ki afi igboiya wa si ibi ite ore-ofe"
- Heb.4:16




1.  SA wo ite anu! 

     Oro Re pe mi wa, 

     Nibe Jesu f’oju ‘re han 

     Lati gbo adura.


2.  Eje etutu ni,

     Ti a ti ta sile

     Pese ebe t’o le bori 

     F’awon t’o nt'Olorun.


3.  lfe Re je fun mi 

     Ju bi mo ti fe lo

     A ma fun enti'o bere 

     Ju bi nwon ti nfe Io.


4.  Fun wa l’aworan Re 

     At'oju rere Re

     Jeki nle sin O nihinyi

     Ki mba le ba O gbe.  Amin

English »

Update Hymn