HYMN 426
C.M.S 302 H.C 278 7s. 6s (FE 449)
"Enyin ti gba emi isodomo nipa eyiti awa
fi nke pe, Abba Baba” - Rom. 8:15
1. lWO lsun imole
Ogo ti ko l'okunkun
Aiyeraiye, titi lai
Baba Mimo, gbo tiwa.
2. Kanga iye ti nsan lai
lye ti ko l’abawon
lye to ni irora
Baba Mimo, gbo tiwa.
3. Olubukun Olufe
Omo Re mbe O loke
Emi Re nrado bo wa
Baba Mimo. gbo tiwa.
4. Y'ite safire Re ka
L'osumare ogo ntan
O kun fun alafia
Baba Mimo, gbo tiwa.
5. Niwaju ‘te anu Re
L'awon Angeli npade
Sugbon wo wa lese Re
Baba Mimo, gbo tiwa.
6. Iwo a okan Re nyo
S'amusua t'o pada,
T'o mo ‘rin re lokere
Baba Mimo, gbo tiwa.
7. Okan ti nwa isimi
Okan t’eru ese npa
B'om’ owo ti nke f 'omu
Baba Mimo, gbo tiwa.
8. Gbogbo wa ni alaini
L’ebi, l’ongbe at‘are
Ko si ede f'aini wa
Baba Mimo, gbo tiwa.
9. Isura opolopo
Ko lo kojo bi Oba?
Ainiye, aidiyele?
Baba Mimo, gbo tiwa.
10. ‘Wo ko da omo Re si
Omo Re kansoso na,
Tit'O fi par‘ise Re,
Baba Mimo, gbo tiwa. Amin
English »Update Hymn