C.S.M 537 T.C.H 51 L.M (FE 447) "Omo Olorun ye, o si li agbara" - Heb.4:12 1. JE ki ilekun aitase Si fun ise wa, Oluwa Ti o si ti ki o ti mo Ilekun ‘wole oro re. 2. F‘owo ina to ete won Ti nfi’ lana Re han aiye F'ife mimo si aiya won Ti Olorun at'enia. 3. F'itara fun iranse Re, T’ohun kan ko le mu tutu Bi nwon si ti ntan oro Re Bukun imo at’ise won. 4. Ran Emi Re lat'oke wa Ma je ki agbara Re pin Tit'irira o fi pari, Ti gbogbo ija o si tan. Amin